aje

aje

Aje Karo o Aje olokun Ogugu luso Aje oniso booji Asewe dagba Asagba dewe Eni ti eru ati omo n fi ojojumo wa kiri Iwo ni labomon ti bori aye Aje Iwo lajiki Aje Iwo lajige Aje Iwo lajipe Eni amusokun Eni amusede Iwo lani ra opolo aran aso oba ti kona yanranyanran Aje...
Esta web utiliza cookies, puede ver aquí la Política de Cookies