Ìrosùn Òsá

Hay que sacrificarle a Orí con un gran pez.

Nunca deberá olvidarse de sus benefactores, porque sucederá algo inolvidable en su vida.

Èkùró oríta méta ni ò sẹnu sợnsợ sólóko
A dífá fún Òrúnmìlà
Níjí ti ń lợ rèé yanrí lóde Ìdó Yóó si yan iwà lójà Èjìgbòmẹkùn Wón ní kí Bàbá ó rúbợ
Ńgbà Òrúnmìlà dé òde Ìdó
Ó yanríi tiè
Níjó a bá si yanrí lóde Ìdó A à gbợdò nájà níjó òhún Báa bá yanrí lódún yìí
Ó dèèmíin ká tóó lợ ợjà Èjìgbòmẹkùn
Ká tó lòó ra iwà
Níjó a bá si nájà
A à gbợdò yanrí lójó òhún
Déédé igbà tí wón ó si yanrí tán ni inájà náà ó parí
Şùgbón àwợn ợmợ èdá ò gbóràn
Òrúnmìlà yanrí è tán Ó tún yàn fún ợmợ èdá Ó wá ní ẹ móợ ní sùúrù Níjó téẹ bá yanrí
Ệ mó nàájà
Èèkan kúkú lèèyán ó yanrí è
Bó bá si si di èèmíin
Ệ móợ bò wá si ợjà Èjìgbòmẹkùn
Kéẹ si yan iwà
Ohun gbogbo táàá fíí şe ilé ayé
Bí owó

Aya rere
Ợmợ
Ilé àti béé béé lợ
Làá pè níwà
Béèyán bá lóun ó şe méjèèjì pò
Yóó pòfo méjèèjì ni Orí làá kókóợ yàn Ká tó lòó yan iwà Ayé yẹ Òrúnmìlà
Ayé si yẹ ợmợ èèyàn
Òrúnmìlà wá ń jó ni ń yò Ní ń yin àwợn Babaláwo Àwợn Babaláwo ń yin Ifá
Ó ní béè làwợn Babaláwo tòún wí
Èkùró oríta méta ni ò sẹnu sợnsợ sólóko
A dífá fún Òrúnmìlà
Níjí ti ń lợ rèé yanrí lóde Ìdó Yóó si yan iwà lójà Èjìgbòmẹkùn Èlà nikàn ló níwà rere
Àwợn tó yanrí ò níwà lówó
Èlà nikàn ló níwà rere.

 

Èkùró oríta méta ni ò sẹnu sợnsợ sólóko

Lanzó Ifá para Òrúnmìlà, el día en que venía a escoger Orí en la ancestral ciudad de Ìdó y a escoger su carácter en el mercado de Èjìgbòmẹkùn.

Le dijeron que debía sacrificar.

Cuando Òrúnmìlà llegó a la ciudad de Ìdó, él escogió su Orí, pero el día que se escoge el Orí, no se puede ir al mercado a escoger el carácter.

Si uno escoge un Orí este año, escogerá el año próximo para ir al mercado de Èjìgbòmẹkùn a escoger el carácter.

Al igual sucede a la inversa, que no se puede escoger el Orí, el día que se escoge el carácter, pues los sitios serán cerrados cuando se escoge una de las dos alternativas.

Òrúnmìlà escogió su Orí y el de los hombres y le pidió paciencia, pero ellos no le escuchaban.

Si uno escoge un Orí este año, escogerá el año próximo para ir al mercado de Èjìgbòmẹkùn a escoger el carácter, les explicó.

Solo una vez se escoge el Orí en la vida.

En la próxima estación se irá al mercado y se escogerá el carácter y todas las demás cosas de la vida, como la riqueza, esposas, hijos, casas, respeto, propiedades, títulos, honor, etc.

Son las cosas que se refieren y dan una métrica de nuestro carácter, conducta y personalidad.

Si uno decide o trata de escoger Orí y carácter al mismo tiempo, tiene muchas posibilidades de perder las dos alternativas.

Si uno escoge un Orí este año, escogerá el año próximo para ir al mercado de Èjìgbòmẹkùn a escoger el carácter.

La vida le fue confortable a Òrúnmìlà.

Él alabó a sus babaláwos y ellos alabaron a Ifá.

Èkùró oríta méta ni ò sẹnu sợnsợ sólóko Lanzó Ifá para Òrúnmìlà, el día en que venía a escoger Orí en la ancestral ciudad de Ìdó y a escoger su carácter en el mercado de Èjìgbòmẹkùn.

Le dijeron que debía sacrificar.

Es Èlà quien posee buenos caracteres y personalidades.

Aquellos que escogen solo su Orí, no poseen buen carácter.

Es Èlà quien posee buenos caracteres y personalidades.

Wónná wónná o kú megi
O kú megi ni beé Wònnà wónná o kú megi O kú megi ni beé
Àrìrà òkè níí béjíí rin
Níí múná lówó
Àrìrà òkè níí béjíí rin Níí túmò eji yagbayagba A dífá fún Gbàjà Ìròkò
Èyí ti ń lợ rèé tẹ Şàngó nífá
Ó ní ipáa Şàngó ó kàá nňkan
Ipáa rè ó kàlé ayé àtòde òrun
Ó lénikan ò níí kápáa Şàngó mó láyé Gbàjà Ìròkò bá tẹ Şàngó nífá Şàngó bá nípợn
Bó bá saara látòde òrun
Gbogbo èèyàn ó si móợ gbòn láyé
Ayé yẹ é
N ní wá ń jó ni ń yò
Ní ń yin àwợn Babaláwo
Àwợn Babaláwo ń yin Ifá
Ó ní béè làwợn Babaláwo tòún wí
Wónná wónná o kú megi
O kú megi ni beé Wònnà wónná o kú megi O kú megi ni beé
Àrìrà òkè níí béjíí rin
Níí múná lówó
Àrìrà òkè níí béjíí rin

Níí túmò eji yagbayagba A dífá fún Gbàjà Ìròkò Èyí ti ó tẹ Şàngó nífá Şàngó bóo bá jợba tán Dákun mó gbàgbé Awo
Gbàjà Ìròkò ló tẹ Şàngó nífá
Gbàjà Ìròkò a ri ợ rólà yí pẹrẹngẹdẹ Mo şe bíwợ ló tẹ Şàngó nífá Gbàjà Ìròkò.

 

Wónná wónná o kú megi
O kú megi ni beé
Wònnà wónná o kú megi
O kú megi ni beé

El trueno acompaña una tormenta y llega con el relámpago.
El trueno acompaña una tormenta y forma
torrenciales aguaceros.
Lanzaron adivinación para Gbàjà Ìròkò, que venía a iniciar a Şàngó en el culto de Ifá.
Le dijo a Şàngó que haría cosas que serían
difundidas en el Cielo y en la Tierra y que nadie podría detenerlo ni resistírsele.
Y Gbàjà Ìròkò, convirtió a Şàngó en un sacerdote de Ifá y la deidad devino con mucha más fortaleza que antes.
Una vez lanzaba sus truenos en el Cielo, todos se
estremecían en la Tierra.
Él bailó y alabó a sus babaláwos y ellos alabaron a Ifá.

Wónná wónná o kú megi
O kú megi ni beé
Wònnà wónná o kú megi
O kú megi ni beé

El trueno acompaña una tormenta y llega con el relámpago.

El trueno acompaña una tormenta y forma torrenciales aguaceros.

Lanzaron adivinación para Gbàjà Ìròkò, que venía a iniciar a Şàngó en el culto de Ifá.

Şàngó si últimamente, te has convertido en rey poderoso.

¡No olvides a tus sacerdotes, por favor!

Gbàjà Ìròkò, convirtió a Şàngó en un sacerdote de Ifá.

Gbàjà Ìròkò,te vemos en tu abundante riqueza.

Eres quien inició a Şàngó en el culto de Ifá Gbàjà Ìròkò.

Ìrosùn Òsá
Califica esta publicación