Ìrosùn Ìká

 

Dice Ifá que esta persona viaja mucho, que no deberá revelar a nadie, el día de su partida.

Ha sido capaz de hacer dinero en sus viajes y alguien está tratando  de  robarle a  su regreso, deberá ofrendar con su ropa y buscar la  manera de enmascararse para no ser reconocido  al  regresar.

Él  debe  ser o estar  vigilante  del  tiempo  que está visitando  a  su pariente  político ya que hay algunos que quieren hacer intimar a su esposa con alguien más en su ausencia.

 

Èrò mó sùn ká

Èrò mòmò şe sun bèbè

A dífá fún Òrúnmìlà Níjó ti ń sawoó relé Ìjerò Òrúnmìlà ni ń relé Ìjerò Wón ní kó rúbợ

Ńgbà ti bàbá dé ilé Ìjerò

Òrúnmìlà bá bèrè síí pá ajé

Ó lówó lợwợ

Àwn ti ón ń bẹ níbè bá ń pète pèrò

n ń pé láti inú ilú àwn

N leléyìí ó ti kó ajé tó tó báyìí jáde Yóó si kó gbogbo è lợ sí òkè igètí ilú Bàbá è

Wón ló dáa

Ệ móợ só igbà ti ó bàá lợ Òrúnmìlà wáá sùn Oorun rè ò já geere

Ó bá bí òkè ipòrí è leeré

Súkù sákà gbèje gbèjErín ńlá yợ kàngí lójú pón Wón ri Ìrosùn lówó òtún Ìká lówó òsi

n níwợ Òrúnmìlà

Bóo bá ń relé

Ó ò gbợdò dá gbére fénìkan Bójó tóó lợ bá ti ku márùún Méwàá ní ó móợ pè é fún wợn

n ní kí Òrúnmìlà ó dá èwù miíin

Kó si lòó bợ Ògún

n ní kí Òrúnmìlà ó wợ èwù  d

Òrúnmìlà şe gbogbo è

Wón ní kó tójú apirù

Àwn ợdẹ ni wón ó si yàn mú Òrúnmìlà Pé kí wón ó lòó gợ sórí igi ti ń bẹ lónà ibi Òrúnmìlà ó gbà

n ní kí wón ó dá Òrúnmìlà lóKí  wón ó si gba èrù lórí è Òrúnmìlà bá pèwù dà

Kò şánsợ módìí

Ó bợ sòkòtò gíri

Ợjó márùún lÒrúnmìlà dá fún wn

Ợjó kẹta ló kúrò ńlé Ńgbà ó bóóde to rin jinnà Ló sun Ìjálá

Ló ní gbogboo yìn ni mo kí ò

N ò lólódi kan ợdẹ Èròmósùnká ẹ mómòợ şe sun bèbè Ệ mómò şe sun bèbè ò ó o dilé Ìjerò kokooko ká tóó móju boorun

Ńbo lè ń gbé ńbo lèèyín wà

Gbogboo yìn pátápátá aráluwà èyí í sòwò èjè

n ń póokú Bàbá

Ňlé Bàbá Ológùún Òrúnmìlà kúrò ni Bàbá Awo Ó di Bàbá ợdẹ

Ó tun rin sàà

Ó ni gbogboo yin ni mo kí ò n ò lólódi kan ợdẹ

Mo ki yín tèsótèsó

Mo ki yín tolóógun tolóógun Àtàgbààgbàà tí ń bẹ nífè oòyè Ệ móợ gbó ò.

Níbo lè ń gbé níbo lèèyín wà gbogbo

ẹlégbé d

Ợdẹ ń lợ lónìí ò; ợdẹ ń l

Mósùnká ẹ mòmò şe sun bèbè

Ó dilé Ìjerò kokooko ká tóó mójú boorun

Aráluwà èyí tíí sòwò èjè Wón ń pé ookú Bàbá Òrúnmìlà tún yè ségbèé kan Ó tún ń ba ibòmíin lợ

Ló tún sun Ìjálá

Ó ní mo dé báàá tíí dé ò

Bí  edè tíí dé ò Gbogboo yín ni mo kí ò Ibi  téẹ bá wá ẹ si wí Gbogboo yín ni mo kí ò Èmi ò lólódi kan ợdẹ

Mo mòó ké

Béè ni mo mòó hàn Gbogbo gégé ẹnu ợdẹ níí şe Mo ríbi gbé e sí ò

Mo si rónà gbé gbà

Mó rónà gbé gbà

Ệjó ń bẹ lénu bí ợmợ sáoko Mo ródò àgbààgbà kéjóò mi lGbogbo àgbààgbà ti ń bẹ nílè yìí pápátá

Ni  wón sẹjóò mi dàre

Ńbo lè ń gbé aráluwà èyí tíí sòwò èjè

n ń póokú Bàbá

Wón  ń kí Òrúnmìlà lótùún lósi

Ó tún wí Yóó bàyá onílù A bàyá oníjó ò

A bàyá òdàdà tó féé dahùn ẹnuù mi

Wn ò pé n gbénu sóhùún mó pé ẹnuù mí ń rùn

Mo toàròyé

Mo gbénu lợ rèé fálágbàf

Àwn fálágbàfợ gbogbo ti ń bẹ ńlè yí pá

Gbogbo wón gbẹgbàá lówóò mi Èèyàn ò pé n gbénu sóhùún mó Pé ẹnuù mí ń rùn

Ńgbà Òrúnmìlà dé ibodè

Ó bá paşợ dà

Ìgbà tílè mó

n dé inú ilé wợn ò bá Òrúnmìlà mó

Wón ní áà

Àşé Bàbá yìí ní ń sun Ìjálá lợ lálé à? Ibi ti Babaláwo ti gbợdò mợ gbogbo è é şe nùu

Apirù lásán làwợn rí lórùun rè

Ló si wợ èwù d

Àşé Bàbá yìí ní ń l.

Èrò mó sùn ká

Èrò mòmò şe sun bèbè

Lanzó adivinación para Òrúnmìlà, cuando se dirigía a  ejercer  el  sacerdocio  en la  ciudad  de Ìjerò.  Le dijeron que ofrendara.

Cuando llegó a esa ciudad, comenzó a hacer dinero, de forma tal que sus cantidades acumuladas  en tan poco tiempo, trajeron el descontento de algunos de sus habitantes.

Ellos observaban  que sus ganancias, él  las enviaba a la ciudad de su padre Òkè Igètí y concluyeron que un día tendría que regresar allá  y resolvieron estar vigilantes al día de su partida a casa.

Esa noche, Òrúnmìlà tuvo pesadillas y sondeó a Ifá buscando la causa y Ìrosùn Ìká  apareció en el tablero.

E Ifá  le  dijo que cuando llegase  el  día de su regreso a  casa, no le dijese a  nadie, acerca de ello, que  si faltaban cinco días, dijese que eran diez.

Y  que debería recoger toda su ropa usada y ofrecérsela en sacrificio a Ogún.

También debía conseguir la ropa y trajes de un cazador.

Òrúnmìlà lo hizo todo al pie de la letra y preparó un apirù  (especie  de  látigo, o bastón  usado  por los cazadores para eliminar moscas e    insectos voladores.

Usado como bastón de identificación).

Sus enemigos habían instruido a algunos cazadores que emboscaran a Òrúnmìlà entre  los bosques, el día de su regreso y le robaran sus riquezas y pertenencias.

Òrúnmìlà anunció que partiría dentro de cinco días ellos se emboscaron a su espera a los tres días, sin saber que él disfrazado de cazador, se paseó entre ellos y cantó una larga canción de Ìjálá  (canción de alabanza a los cazadores y sus proezas).

En esa canción,les descubría, como se había enterado de sus intenciones, que no eran las más justas  y como sabiendo  esto, el  consejo ancestral que él siempre consultaba, le había autorizado a traficar con sangre, que sería la de ellos, si le hacían daño, etc.

Por supuesto, ellos creyeron que Òrúnmìlà se había convertido en un heroico cazador y había dejado de ser adivino y no le hicieron ningún    ataque, dejándole así escapar sin apercibirse de que era él quien cantaba esa canción tan profunda.

Y es por esta razón que los babaláwos deben ser versátiles  en sus conocimientos y expresar a través de sus labios siempre sociables, las mejores experiencias y consejos en la vida.

Cuando un babaláwo va al límite entre el campo y la ciudad, debe cambiarse de ropa, acorde a la función que va a realizar.

Las personas que quisieron verlo al día siguiente, no le hallaron y dijeron: ¡Hàáà, ese fue el hombre que cantó esa larga canción de Ìjálá, ayer en la noche!

Y es por esta razón que los babaláwos  deben ser versátiles.

  • ¡Pero fue el apirù que vieron sobre sus hombros!
  • ¡Él se vistió como un cazador!
  • ¡Eso  fue lo que fingió ser ese hombre!

 

Òpó ti ń bẹ ńnú ilé yìí abinú gbèdugbèdu

A dífá fún Olúáwo

Níti ń lợ si Àgbá ègbò ifè Olúkiribí

Èyí  ti ń lợ rèé fé Gégélóşe Ợmợợ wợn lóde Òhan Wón ní kí Olúáwo ó rúbợ Olúáwo fé Gégélóşe tán Bàbá è bá kú

n bá ránşẹ sí Olúáwo

Pé ó móợ bò Kó wáá húsin Olúáwo si ní akan

Ệfun ni ń bẹ lójú kan òtún è

Àti Àgùtàn kan tó kùn lósùn lésè kan òsi

Gégélóşe ló kókó dé ibi òkú Olúáwo ó móợ bò ńgbòó bá dijó ináwó Ìyàwóo rè bá gbó ijàňbá táwợn kan ń pète

Wón féé şe Olúáwo ni jàňbá lójó ihúsin Ìyàwó bá lòó dúó lójú ònà Olúáwo à sun

Oorun rè ò já gaara

Ó bá gbe òkè ìpòrí è kalè Wón ó rifá méjì Èròmósùnká ni ón ri Wón níwợ Olúáwo

Bó bá ń l

Ajá tóo kùn léfun lójú kan òtún

Àti Àgùtàn kan tóo kùn lósùn lésè kan òsi

Àwn méjèèjì ni kóo ti síwájú

Kíwợ náà ó móợ bò léyìn Obìnrin rè si ti gợ sójú ònà ti ń wo Olúáwo

Obìnrin bá rí ajá Olúáwo tó yợ lóòókán

Ló bá ké Ìjàsì

Ó léẹkú ò ợmợ Àgbợnnìrègún gbogbo babaláwo

n ni Hín

Òpó ti ń bẹ ńnú ilé yìí abinú gbèdugbèdu A dífá fún Olúáwo ti ń lợ Àgbá ègbò ifè Olúkiribítí

Hín

Ń lợ rèé fé Gégélóşe ợmợợ wợn lóde

Òhan

Hín

Bàbá Gégélóşe á kú wón lÓlúáwo ó móợ bò wá húsin

Hín

Mo rájá Olúáwo tó kẹfun lójú kan òtún

Hín

Àgùtàn Olúáwo kosùn lésè kan òsi o

Hín

Ệ wí fún Olúáwo pé ó mó wợ ilè yí wá

Hín

Kó mó şe sùn ká o, kó mó mó şe fún bèbè o

Hín

Ilé Ìjerò kokooko ní ó móợ l

Hín

Mó sún ká o mó şe sun bèbè o, ó dilé Ìjerò kokooko kó o tóó fojú boorun Hín

Olúáwo gbòjègé Awo si ń lợ ò o ò o ò Olúáwo gbòjègé Awo si ń lợ ò ò ò ò Olúáwo gbòjègé Awo si ń lợ o o o o Olúáwo gbòjègé Awo si ń lợ ợ ợ ợ .

El pilar de esta casa se le está pandeando  el estómago.

Lanzó adivinación para Olúáwo, cuando venía  hacía Àgbá ègbò ifè Okiribítí.

El que iba a casarse con Gégélóşe, su hija en la ciudad de Òhan.

Ellos le pidieron a él que sacrificara.

Gégélóşe es la esposa de Olúáwo.

Su padre había muerto y él debía venir para dirigir los rituales del funeral.

Olúáwo tenía un perro, que fue pintado de color blanco en la parte derecha de su rostro y una oveja que fue pintada de color osùn en su pata izquierda. Gégélóşe había escuchado acerca de cosas malignas que se planeaban contra su esposo y se dirigió a su encuentro antes de que él ejecutase los ceremoniales.

Él había dormido muy mal y soñó con su propio Ifá “Ìrosùn  Ìká”  que le  decía: – ¡Durante la  ceremonia, deja  que vayan delante  de ti,  el  perro y la  oveja pintados! 

La esposa,había estado buscándolo afanosamente y cuando divisó a los dos animales desde lejos, rompió a cantar una canción Ìjálá:

 ¡Saludo a todos los hijos Àgbợnnìrègún de todos los Babaláwos!

Y ellos respondieron:

 ¡Hín! 

 El pilar de esta casa se le está pandeando el estómago.

Lanzó adivinación para Olúáwo, cuando venía hacía Àgbá ègbò ifè Olúkiribítí 

 ¡Hín! 

El que iba a casarse con Gégélóşe, su hija en la ciudad de Òhan 

¡Hín! 

Su padre había muerto y él debía venir para dirigir los rituales del funeral 

 ¡Hín! 

 Yo puedo ver el perro de Olúáwo con un ojo pintado de blanco 

 ¡Hín! 

Y veo a la oveja de Olúáwo con una pierna pintada con osùn 

 ¡Hín! 

 Por favor,díganle a Olúáwo que no entre a esta ciudad 

 ¡Hín! 

 Ni que tampoco pernocte o duerma en sus alrededores 

 ¡Hín! 

 Él deberá seguir camino recto a Ìjerò

 ¡Hín!

 Hasta que no llegues a Ìjerò, no te permitas descansar ni dormir a la  intemperie o en  los alrededores 

¡Hín! 

Olúáwo escuchó, y está saliendo y también está cantando 

Olúáwo escuchó, y está saliendo Olúáwo escuchó, y está saliendo.

 

 

 

Ìrosùn Ìká
Califica esta publicación